Tsung-Dao Lee

Tsung-Dao Lee tàbí T.D. Lee, (bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún Oṣù kọkànlá Ọdún 1926) jẹ́ aṣisẹ́olóhungidi ọmọ orílẹ̀ èdè China ará Amẹ́ríkà tó gba Ẹ̀bùn Nobel nínú ìmọ̀ Physics ní ọdún 1957.


From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy